1 Tímótíù 3:7 BMY

7 Ó sì yẹ kí ó ni ẹ̀rí rere pẹ̀lú lọ́dọ̀ àwọn tí ń bẹ lóde; kí ó má baà bọ́ sínú ẹ̀gàn àti sínú ìdẹ́kun Èṣù.

Ka pipe ipin 1 Tímótíù 3

Wo 1 Tímótíù 3:7 ni o tọ