2 Pétérù 1:1 BMY

1 Símónì Pétérù, ìránṣẹ́ àti Àpósítélì Jésù Kírísítì,Sí àwọn tí ó gba irú iyebíye igbàgbọ́ kan náà pẹ̀lú wá nínú òdodo Ọlọ́run wa àti ti Jésù Kírísítì Olùgbàlà.

Ka pipe ipin 2 Pétérù 1

Wo 2 Pétérù 1:1 ni o tọ