2 Pétérù 1:18 BMY

18 Àwa pẹ̀lú sì gbọ́ ohun yìí tí ó ti ọ̀run wá nígbà tí àwa wà pẹ̀lú rẹ̀ ní orí òkè mímọ́ náà.

Ka pipe ipin 2 Pétérù 1

Wo 2 Pétérù 1:18 ni o tọ