2 Pétérù 1:9 BMY

9 Ṣùgbọ́n ẹni tí ó bá ṣe aláìní nǹkan wọ̀nyí, kò lè ríran ní òkèèrè ó fọjú, ó sì ti gbàgbé pé a ti wẹ òun nù kúrò nínú ẹ̀ṣẹ̀ rẹ̀ àtijọ́.

Ka pipe ipin 2 Pétérù 1

Wo 2 Pétérù 1:9 ni o tọ