2 Pétérù 2:17 BMY

17 Àwọn wọ̀nyí ni kànga tí kò ní omi, ìkuuku tí ẹ̀fúúfù ń gbá kiri; àwọn ẹni tí a pa òkùnkùn biribiri mọ́ dè títí láé.

Ka pipe ipin 2 Pétérù 2

Wo 2 Pétérù 2:17 ni o tọ