2 Pétérù 2:6 BMY

6 Tí ó sọ àwọn ìlú Sódómù àti Gòmórà di eérú, nígbà tí ó fi ìparun pátapáta dá wọn lẹ́bí, tí ó fi wọ́n ṣe àpẹẹrẹ fún àwọn tí yóò jẹ́ aláìwà-bí-Ọlọ́run.

Ka pipe ipin 2 Pétérù 2

Wo 2 Pétérù 2:6 ni o tọ