2 Pétérù 2:8 BMY

8 (nítorí ọkùnrin olóòótọ́ náà bí ó ti ń gbé àárin wọn, tí ó ń rí tí ó sì ń gbọ́, lójoojúmọ́ ni ìwà búburú wọn ń bá ọkàn òtítọ́ rẹ̀ jẹ́)

Ka pipe ipin 2 Pétérù 2

Wo 2 Pétérù 2:8 ni o tọ