2 Pétérù 3:12 BMY

12 Kí ẹ máa reti kí ẹ sì máa múra gírí de dídé ọjọ́ Ọlọ́run, nítorí èyí tí àwọn ọ̀run yóò gbiná, tí wọn yóò di yíyọ́, tí àwọn ìmọ́lẹ̀ rẹ̀ yóò sì ti inú ooru gbígbóná gidigidi di yíyọ́.

Ka pipe ipin 2 Pétérù 3

Wo 2 Pétérù 3:12 ni o tọ