2 Pétérù 3:5 BMY

5 Nítorí èyí ni wọ́n mọ̀ọ́mọ̀ ṣe àìfẹ́ẹ́ mọ̀ pé nípa ọ̀rọ̀ Ọlọ́run ni àwọn ọ̀run ti wà láti ìgbà àtijọ́ àti tí ilẹ̀ yọrí jáde nínú omi, tí ó sì dúró nínú omi.

Ka pipe ipin 2 Pétérù 3

Wo 2 Pétérù 3:5 ni o tọ