7 Ìfẹ́ rẹ ti fún mi ní ayọ̀ púpọ̀ àti ìgboyà, nítorí ìwọ, arákùnrin ti tu ọkàn àwọn ènìyàn mímọ́ lara.
Ka pipe ipin Fílímónì 1
Wo Fílímónì 1:7 ni o tọ