Fílípì 1:13 BMY

13 Nítorí ìdí èyí, ó ti hàn gbangban sí gbogbo àwọn ẹ̀sọ́ ààfin àti sí àwọn ẹlòmíràn wí pé mo wà nínú ìdè fún Kírísítì.

Ka pipe ipin Fílípì 1

Wo Fílípì 1:13 ni o tọ