Júdà 1:13 BMY

13 Wọ́n jẹ́ ìjì líle ti ń ru ní ojú omi òkun, ti ń hó ìfófó ìtìjú wọn jáde; alárìnkiri ìràwọ̀, àwọn tí a pa òkùnkùn biribiri mọ́ dè láéláé.

Ka pipe ipin Júdà 1

Wo Júdà 1:13 ni o tọ