12 Ọ̀kan nínú àwọn wòlíì wọn pàápàá sọ wí pé, “òpùrọ́ ní àwọn ará Kírétè, wọ́n jẹ́ ẹranko búburú tí kò sé tù lójú, ọ̀lẹ, oníwọ̀ra”.
Ka pipe ipin Títù 1
Wo Títù 1:12 ni o tọ