Títù 3:14 BMY

14 Àwọn ènìyàn nílò láti kọ́ bí a tí ń fi ara ẹni jìn sí iṣẹ́ rere kí wọn baà le pèsè ohun kòsémánìí fún ara wọn, nípa èyí, wọn kì yóò jẹ́ aláìléso.

Ka pipe ipin Títù 3

Wo Títù 3:14 ni o tọ