15 Ẹ gbé! Ẹ̀yin tí ẹ fi ibinu fún aládùúgbò yín ní ọtí mu, tí ẹ jẹ́ kí inú wọn ru, kí ẹ lè rí ìhòòhò wọn.
Ka pipe ipin Habakuku 2
Wo Habakuku 2:15 ni o tọ