Habakuku 3:10 BM

10 Nígbà tí àwọn òkè ńlá rí ọ,wọ́n wárìrì;àgbàrá omi wọ́ kọjá;ibú òkun pariwo,ó sì gbé ọwọ́ rẹ̀ sókè.

Ka pipe ipin Habakuku 3

Wo Habakuku 3:10 ni o tọ