Hagai 1:13 BM

13 Ni Hagai, òjíṣẹ́ OLUWA, bá jẹ́ iṣẹ́ tí OLUWA rán an sí àwọn eniyan náà pé òun OLUWA ní òun wà pẹlu wọn.

Ka pipe ipin Hagai 1

Wo Hagai 1:13 ni o tọ