Jona 1:9 BM

9 Ó bá dá wọn lóhùn pé: “Heberu ni mí, ẹ̀rù OLUWA ni ó bà mí, àní Ọlọrun ọ̀run, tí ó dá òkun ati ilẹ̀ gbígbẹ.”

Ka pipe ipin Jona 1

Wo Jona 1:9 ni o tọ