3 Nítorí pé, ó gbé mi jù sinu ibú, ní ààrin agbami òkun,omi òkun sì bò mí mọ́lẹ̀;ọwọ́ agbára rírú omi òkun rẹ̀ sì ń wọ́ kọjá lórí mi.
Ka pipe ipin Jona 2
Wo Jona 2:3 ni o tọ