Mika 1:14 BM

14 Nítorí náà, ẹ óo fún àwọn ará Moreṣeti Gati ní ẹ̀bùn ìdágbére; ilé Akisibu yóo sì jẹ́ ohun ìtànjẹ fún àwọn ọba Israẹli.

Ka pipe ipin Mika 1

Wo Mika 1:14 ni o tọ