Mika 2:9 BM

9 Ẹ lé àwọn aya àwọn eniyan mi jáde kúrò ninu ilé tí wọ́n fẹ́ràn; ẹ sì gba ògo mi kúrò lọ́wọ́ àwọn ọmọ wọn títí lae.

Ka pipe ipin Mika 2

Wo Mika 2:9 ni o tọ