Mika 3:4 BM

4 Nígbà tí ó bá yá, wọn yóo ké pe OLUWA, ṣugbọn kò ní dá wọn lóhùn; yóo fi ojú pamọ́ fún wọn, nítorí nǹkan burúkú tí wọ́n ṣe.

Ka pipe ipin Mika 3

Wo Mika 3:4 ni o tọ