Mika 3:7 BM

7 A óo dójúti àwọn aríran, ojú yóo sì ti àwọn woṣẹ́woṣẹ́; gbogbo wọn yóo fi ọwọ́ bo ẹnu wọn, nítorí pé, Ọlọrun kò ní dá wọn lóhùn.

Ka pipe ipin Mika 3

Wo Mika 3:7 ni o tọ