Mika 7:13 BM

13 Ṣugbọn ayé yóo di ahoro nítorí ìwàkiwà àwọn tí wọn ń gbé inú rẹ̀; àní nítorí iṣẹ́kíṣẹ́ ọwọ́ wọn.

Ka pipe ipin Mika 7

Wo Mika 7:13 ni o tọ