Sefanaya 1:15 BM

15 Ọjọ́ ibinu ni ọjọ́ náà yóo jẹ́, ọjọ́ ìpọ́njú ati ìrora, ọjọ́ ìyọnu ati ìparun, ọjọ́ òkùnkùn ati ìbànújẹ́, ọjọ́ ìkùukùu ati òkùnkùn biribiri.

Ka pipe ipin Sefanaya 1

Wo Sefanaya 1:15 ni o tọ