Sefanaya 2:11 BM

11 OLUWA óo dẹ́rùbà wọ́n, yóo sọ gbogbo oriṣa ilé ayé di òfo, olukuluku eniyan yóo sì máa sin OLUWA ní ààyè rẹ̀ ní gbogbo orílẹ̀-èdè.

Ka pipe ipin Sefanaya 2

Wo Sefanaya 2:11 ni o tọ