14 Ẹ kọrin sókè, kí ẹ sì hó;ẹ̀yin ọmọ Israẹli!Ẹ máa yọ̀ kí inú yín sì dùn gidigidi,ẹ̀yin ará Jerusalẹmu!
Ka pipe ipin Sefanaya 3
Wo Sefanaya 3:14 ni o tọ