Filipi 2:17 BM

17 Ṣugbọn bí a bá fi mí ṣe ohun ìrúbọ ati ohun èèlò ninu ìsìn nítorí igbagbọ yín, ó dùn mọ́ mi, n óo sì máa yọ̀ pẹlu gbogbo yín.

Ka pipe ipin Filipi 2

Wo Filipi 2:17 ni o tọ