Filipi 2:4 BM

4 Ẹ má máa mójútó nǹkan ti ara yín nìkan, ṣugbọn ẹ máa mójútó nǹkan àwọn ẹlòmíràn náà.

Ka pipe ipin Filipi 2

Wo Filipi 2:4 ni o tọ