Jakọbu 1:15 BM

15 Nígbà tí ìfẹ́kúfẹ̀ẹ́ bá lóyún, á bí ẹ̀ṣẹ̀; nígbà tí ẹ̀ṣẹ̀ bá gbilẹ̀ tán á bí ikú.

Ka pipe ipin Jakọbu 1

Wo Jakọbu 1:15 ni o tọ