Jakọbu 2:25 BM

25 Ṣebí bákan náà ni Rahabu aṣẹ́wó gba ìdáláre nípa iṣẹ́, nígbà tí ó ṣe àwọn amí ní àlejò, tí ó jẹ́ kí wọ́n bá ọ̀nà mìíràn pada lọ?

Ka pipe ipin Jakọbu 2

Wo Jakọbu 2:25 ni o tọ