Jakọbu 2:4 BM

4 Ǹjẹ́ ẹ kò fi bẹ́ẹ̀ dá ìyapa sílẹ̀ láàrin ara yín, ǹjẹ́ ẹ kò sì máa ṣe ìdájọ́ pẹlu èrò burúkú.

Ka pipe ipin Jakọbu 2

Wo Jakọbu 2:4 ni o tọ