Jakọbu 2:6 BM

6 Ṣugbọn ẹ̀ ń kẹ́gàn mẹ̀kúnnù. Ṣebí àwọn ọlọ́rọ̀ níí máa fìtínà yín, tí wọn máa ń fà yín lọ sí kóòtù!

Ka pipe ipin Jakọbu 2

Wo Jakọbu 2:6 ni o tọ