Jakọbu 3:12 BM

12 Ẹ̀yin ará mi, ṣé igi ọ̀pọ̀tọ́ lè so èso olifi, tabi kí àjàrà kó so ọ̀pọ̀tọ́? Ìsun omi kíkorò kò lè mú omi dídùn jáde.

Ka pipe ipin Jakọbu 3

Wo Jakọbu 3:12 ni o tọ