Jakọbu 3:7 BM

7 Gbogbo ẹ̀dá pátá: ati ẹranko ni, ati ẹyẹ, ati àwọn ohun tí ń fàyà fà, ati àwọn ẹran omi, gbogbo wọn ni eniyan lè so lójú rọ̀.

Ka pipe ipin Jakọbu 3

Wo Jakọbu 3:7 ni o tọ