Jakọbu 3:9 BM

9 Ahọ́n ni a fi ń yin Oluwa ati Baba. Òun kan náà ni a fi ń ṣépè fún eniyan tí a dá ní àwòrán Ọlọrun.

Ka pipe ipin Jakọbu 3

Wo Jakọbu 3:9 ni o tọ