Jakọbu 4:14 BM

14 Ẹ kò mọ ohun tí yóo ṣẹlẹ̀ si yín lọ́la. Nítorí ìkùukùu ni yín, tí ó wà fún àkókò díẹ̀, lẹ́yìn náà tí kò ní sí mọ́.

Ka pipe ipin Jakọbu 4

Wo Jakọbu 4:14 ni o tọ