Jakọbu 5:15 BM

15 Adura pẹlu igbagbọ yóo mú kí ara aláìsàn náà yá. Oluwa yóo gbé e dìde, a óo sì dárí àwọn ẹ̀ṣẹ̀ tí ó ti dá jì í.

Ka pipe ipin Jakọbu 5

Wo Jakọbu 5:15 ni o tọ