Jakọbu 5:7 BM

7 Ẹ̀yin ará, ẹ mú sùúrù títí Oluwa yóo fi dé. Ẹ wo àgbẹ̀ tí ó ń retí èso tí ó dára ninu oko, ó níláti mú sùúrù fún òjò àkọ́rọ̀ ati òjò àrọ̀kẹ́yìn.

Ka pipe ipin Jakọbu 5

Wo Jakọbu 5:7 ni o tọ