Juda 1:1 BM

1 Èmi Juda, iranṣẹ Jesu Kristi, tí mo jẹ́ arakunrin Jakọbu ni mò ń kọ ìwé yìí sí àwọn tí Ọlọrun Baba fẹ́ràn, tí Jesu Kristi pè láti pamọ́.

Ka pipe ipin Juda 1

Wo Juda 1:1 ni o tọ