Juda 1:21 BM

21 Ẹ pa ara yín mọ́ ninu ìfẹ́ Ọlọrun. Ẹ máa retí ìyè ainipẹkun tí Oluwa wa Jesu Kristi yóo fun yín ninu àánú rẹ̀.

Ka pipe ipin Juda 1

Wo Juda 1:21 ni o tọ