Timoti Keji 2:16 BM

16 Yẹra fún àwọn ọ̀rọ̀ asán ati ọ̀rọ̀ ìsọkúsọ, nítorí àwọn tí wọ́n fẹ́ràn irú ọ̀rọ̀ wọnyi túbọ̀ ń jìnnà sí ẹ̀sìn Ọlọrun ni.

Ka pipe ipin Timoti Keji 2

Wo Timoti Keji 2:16 ni o tọ