Timoti Keji 4:16 BM

16 Nígbà tí mo níláti jà fún ara mi ní ẹẹkinni, kò sí ẹni tí ó yọjú láti gbèjà mi: gbogbo wọn ni wọ́n fi mí sílẹ̀. Kí Ọlọrun má kà á sí wọn lọ́rùn.

Ka pipe ipin Timoti Keji 4

Wo Timoti Keji 4:16 ni o tọ