Timoti Keji 4:5 BM

5 Ṣugbọn, ìwọ ní tìrẹ, fi ara balẹ̀ ninu ohun gbogbo. Farada ìṣòro. Ṣe iṣẹ́ ìyìn rere. Má fi ohunkohun sílẹ̀ láì ṣe ninu iṣẹ́ iranṣẹ rẹ.

Ka pipe ipin Timoti Keji 4

Wo Timoti Keji 4:5 ni o tọ