Joel 1:2 YCE

2 Gbọ́ eyi, ẹnyin arugbo, si fi eti silẹ, gbogbo ẹnyin ará ilẹ na. Eyi ha wà li ọjọ nyin, tabi li ọjọ awọn baba nyin?

Ka pipe ipin Joel 1

Wo Joel 1:2 ni o tọ