Joel 2:12 YCE

12 Njẹ nitorina nisisiyi, ni Oluwa wi, Ẹ fi gbogbo ọkàn nyin yipada si mi, ati pẹlu ãwẹ̀, ati pẹlu ẹkún, ati pẹlu ọ̀fọ.

Ka pipe ipin Joel 2

Wo Joel 2:12 ni o tọ