Joel 2:24 YCE

24 Ati awọn ilẹ ipakà yio kún fun ọkà, ati ọpọ́n wọnni yio ṣàn jade pẹlu ọti-waini ati ororo.

Ka pipe ipin Joel 2

Wo Joel 2:24 ni o tọ