Joel 3:12 YCE

12 Ẹ ji, ẹ si goke wá si afonifojì Jehoṣafati ẹnyin keferi: nitori nibẹ̀ li emi o joko lati ṣe idajọ awọn keferi yikakiri.

Ka pipe ipin Joel 3

Wo Joel 3:12 ni o tọ