Sef 1:17 YCE

17 Emi o si mu ipọnju wá bá enia, ti nwọn o ma rìn bi afọju, nitori nwọn ti dẹṣẹ si Oluwa: ẹjẹ̀ wọn li a o si tú jade bi ekuru, ati ẹran-ara wọn bi igbẹ.

Ka pipe ipin Sef 1

Wo Sef 1:17 ni o tọ