12 Nitori oju Oluwa mbẹ lara awọn olododo, etí rẹ̀ si ṣí si ẹbẹ wọn: ṣugbọn oju Oluwa nwo awọn ti nṣe buburu.
Ka pipe ipin 1. Pet 3
Wo 1. Pet 3:12 ni o tọ